Ojú ìwé wẹẹbu àkọ́kọ́ Mọ̀ nípa Islam Kinni Idi ti Olohun fi da wa ? (Èdè Yorùbá)
Kinni Idi ti Olohun fi da wa ?

Kinni Idi ti Olohun fi da wa ? (Èdè Yorùbá)

Play
Ṣíṣe àfihàn Àwọn nǹkan ti o wà nínú rẹ̀ pẹ̀lú èdè Lárúbáwá

Kinni Idi ti Olohun fi da wa ? (Èdè Yorùbá)

Èdè: Èdè Yorùbá
Pípèsè: Isa Akindele Solahudeen
Ọ̀rọ̀ ṣókí:
Ibanisoro yi da lori idahun fun ibeere ti o n so pe: kinni idi ti Olohun fi da awa erusin Re? Oniwaasi si dahun ni kukuru wipe nitori ijosin ni Olohun fi da awa eniyan ati alijonnu. Oju ona kan soso ti a si fi le sin Olohun naa ni esin Islam.