Ojú ìwé wẹẹbu àkọ́kọ́ Mọ̀ nípa Islam Ọla ti o nbẹ fun Aluwala ati bi a ti se nse e (Èdè Yorùbá)
Ọla ti o nbẹ fun Aluwala ati bi a ti se nse e

Ọla ti o nbẹ fun Aluwala ati bi a ti se nse e (Èdè Yorùbá)

Play
Ṣíṣe àfihàn Àwọn nǹkan ti o wà nínú rẹ̀ pẹ̀lú èdè Lárúbáwá

Ọla ti o nbẹ fun Aluwala ati bi a ti se nse e (Èdè Yorùbá)

Èdè: Èdè Yorùbá
Pípèsè: Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Ọ̀rọ̀ ṣókí:
Idanilẹkọ yii da lori alaye bi a se nse aluwala ati awọn ẹsan (ọla) ti o nbẹ fun aluwala sise, bakannaa ọrọ nipa awọn ohun ti o nsọ aluwala di ọranyan fun musulumi.