Ojú ìwé wẹẹbu àkọ́kọ́ Mọ̀ nípa Islam Ẹbọ sise: Itumọ rẹ ati Awọn Ipin rẹ (Èdè Yorùbá)
Ẹbọ sise: Itumọ rẹ ati Awọn Ipin rẹ

Ẹbọ sise: Itumọ rẹ ati Awọn Ipin rẹ (Èdè Yorùbá)

Play
Ṣíṣe àfihàn Àwọn nǹkan ti o wà nínú rẹ̀ pẹ̀lú èdè Lárúbáwá

Ẹbọ sise: Itumọ rẹ ati Awọn Ipin rẹ (Èdè Yorùbá)

Èdè: Èdè Yorùbá
Pípèsè: Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Ọ̀rọ̀ ṣókí:
Idanilẹkọ yi da lori wipe idakeji ẹbọ sise ni sise Ọlọhun Allah ni aaso tabi gbigba A ni okan soso pẹlu ẹri Alukuraani ati ẹgbawa hadisi. Alaye tẹsiwaju nipa itumọ ẹbọ sise pẹlu awọn ọna ti ẹbọ sise pin si.