Ojú ìwé wẹẹbu àkọ́kọ́ Mọ̀ nípa Islam Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo (Èdè Yorùbá)
Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo

Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo (Èdè Yorùbá)

Play
Ṣíṣe àfihàn Àwọn nǹkan ti o wà nínú rẹ̀ pẹ̀lú èdè Lárúbáwá

Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo (Èdè Yorùbá)

Èdè: Èdè Yorùbá
Pípèsè: Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Ọ̀rọ̀ ṣókí:
Idanilẹkọ yii da lori awọn koko wọnyii: (i) Iha ti ẹsin ko si Rukiya, Oogun ifẹ ati Gbekude lilo, (ii) Idajọ awọn nkan mẹtẹẹta yii, (iii) Majẹmu Rukiya, (iv) Idajọ wiwe ayah Alukuraani ati dide mọ ọrun, (v) Diẹ ninu awọn Rukiya ti a le fi se isọ fun alaarẹ, ọmọde ati lati fi wa iwosan.