Ojú ìwé wẹẹbu àkọ́kọ́ Mọ̀ nípa Islam Diẹ ninu awọn iwọ Ojise Ọlọhun Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] (Èdè Yorùbá)
Diẹ ninu awọn iwọ Ojise Ọlọhun Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a]

Diẹ ninu awọn iwọ Ojise Ọlọhun Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] (Èdè Yorùbá)

Play
Ṣíṣe àfihàn Àwọn nǹkan ti o wà nínú rẹ̀ pẹ̀lú èdè Lárúbáwá

Diẹ ninu awọn iwọ Ojise Ọlọhun Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] (Èdè Yorùbá)

Èdè: Èdè Yorùbá
Pípèsè: Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Ọ̀rọ̀ ṣókí:
Ojuse awa Musulumi si Anabi wa Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] da lori awọn koko wọnyii: 1. Titẹle asẹ rẹ. 2. Gbigba ọrọ rẹ gbọ ni ododo. 3. Kikọse rẹ ninu iwa, ẹsin ati isesi. 4. Ninifẹ rẹ pẹlu mimaa se asalaatu fun un, ati didaabo bo Sunnah rẹ.