Ojú ìwé wẹẹbu àkọ́kọ́ Mọ̀ nípa Islam Gbigba Kadara gbọ (Èdè Yorùbá)
Gbigba Kadara gbọ

Gbigba Kadara gbọ (Èdè Yorùbá)

Play
Ṣíṣe àfihàn Àwọn nǹkan ti o wà nínú rẹ̀ pẹ̀lú èdè Lárúbáwá

Gbigba Kadara gbọ (Èdè Yorùbá)

Èdè: Èdè Yorùbá
Pípèsè: Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Ọ̀rọ̀ ṣókí:
Itumọ igbagbọ si kadara pẹlu ẹri rẹ lati inu Alukuraani ati Sunnah. Lẹyin naa idahun waye si ibeere yi: “ Njẹ a le fi kadara se ikẹwọ fun ẹsẹ dida bii?”