Ojú ìwé wẹẹbu àkọ́kọ́ Mọ̀ nípa Islam Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a], bi Alukuraani ti se iroyin rẹ (Èdè Yorùbá)
Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a], bi Alukuraani ti se iroyin rẹ

Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a], bi Alukuraani ti se iroyin rẹ (Èdè Yorùbá)

Play
Ṣíṣe àfihàn Àwọn nǹkan ti o wà nínú rẹ̀ pẹ̀lú èdè Lárúbáwá

Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a], bi Alukuraani ti se iroyin rẹ (Èdè Yorùbá)

Èdè: Èdè Yorùbá
Pípèsè: Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Ọ̀rọ̀ ṣókí:
1- Itan Iya Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a] ati itan iya-iya rẹ. 2- Alaye bi wọn se ni oyun Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a] ni ọna iyanu pẹlu bibi rẹ ni ọna iyanu, ti eleyi ko si sọ di Ọlọhun. 3- Ọrọ nipa isẹ ipepe anọbi Isa pẹlu isẹ ayanu rẹ, ati wipe Iru ẹlẹsin wo ni Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a].