Diẹ ninu awọn iwọ Ojise Ọlọhun Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a]
(Èdè Yorùbá)
اللغة:Èdè Yorùbá
إعداد:Abdur Rahman Muhammadul Awwal
نبذة مختصرة:
Ojuse awa Musulumi si Anabi wa Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] da lori awọn koko wọnyii:
1. Titẹle asẹ rẹ.
2. Gbigba ọrọ rẹ gbọ ni ododo.
3. Kikọse rẹ ninu iwa, ẹsin ati isesi.
4. Ninifẹ rẹ pẹlu mimaa se asalaatu fun un, ati didaabo bo Sunnah rẹ.
مشاركة
استخدم رمز الاستجابة السريعة (QR) لمشاركة بيان الإسلام بسهولة مع الآخرين